2 Samuẹli 24:25

2 Samuẹli 24:25 BMYO

Dafidi sì tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀ sí OLúWA, ó sì rú ẹbọ sísun àti ti ìlàjà. OLúWA sì gbọ́ ẹ̀bẹ̀ fún ilẹ̀ náà, ààrùn náà sì dá kúrò ní Israẹli.