Gbogbo ìgbà ni a máa ń fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run nítorí yín, a sì ń gbàdúrà fún un yín nígbà gbogbo pẹ̀lú. A ń rántí yin ni àìsimi nígbà gbogbo níwájú Ọlọ́run àti Baba nípa iṣẹ́ ìgbàgbọ́ yín, iṣẹ́ ìfẹ́ yín àti ìdúró ṣinṣin ìrètí yín nínú Jesu Kristi Olúwa wa.
Kà 1 Tẹsalonika 1
Feti si 1 Tẹsalonika 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: 1 Tẹsalonika 1:2-3
5 Days
Hosanna Wong knows firsthand what feeling unseen, unworthy, and unloved is like. In this 5-day plan, she unpacks nine names God calls you and offers practical, down-to-earth encouragement to help you expose lies, see yourself through God’s lens, and live with a newfound posture and purpose.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò