1 Samuẹli 16:7

1 Samuẹli 16:7 YCB

Ṣùgbọ́n OLúWA sọ fún Samuẹli pé, “Má ṣe wo ti ìrísí rẹ̀ tàbí ti gíga rẹ̀, nítorí èmi ti kọ̀ ọ́ sílẹ̀. OLúWA kì í wo ohun tí ènìyàn máa ń wò. Ènìyàn máa ń wo òde ara ṣùgbọ́n OLúWA máa ń wo ọkàn.”