1 Samuẹli 16:13

1 Samuẹli 16:13 YCB

Nígbà náà ni Samuẹli mú ìwo òróró, ó sì ta á sí i ní orí ní iwájú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀, láti ọjọ́ náà lọ, Ẹ̀mí mímọ́ OLúWA wá sí orí Dafidi nínú agbára. Samuẹli sì lọ sí Rama.