1 Samuẹli 13:12

1 Samuẹli 13:12 BMYO

mo rò pé, ‘Àwọn Filistini yóò sọ̀kalẹ̀ tọ̀ mí wá ní Gilgali nísinsin yìí, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ì tí ì wá ojúrere OLúWA.’ Báyìí ni mo mú ara mi ní ipá láti rú ẹbọ sísun náà.”