1 Ọba 11:9

1 Ọba 11:9 BMYO

OLúWA bínú sí Solomoni nítorí ọkàn rẹ̀ ti yípadà kúrò lọ́dọ̀ OLúWA Ọlọ́run Israẹli, tí ó ti fi ara hàn án lẹ́ẹ̀méjì.