1 Kronika 10:13-14

1 Kronika 10:13-14 YCB

Saulu kú nítorí kò ṣe òtítọ́ sí OLúWA: Kò pa ọ̀rọ̀ OLúWA mọ́ pẹ̀lú, ó tọ abókùúsọ̀rọ̀ lọ fún ìtọ́sọ́nà. Kò sì béèrè lọ́wọ́ OLúWA, bẹ́ẹ̀ ni OLúWA pa á, Ó sì yí ìjọba náà padà sọ́dọ̀ Dafidi ọmọ Jese.