O. Sol 2:16-17

O. Sol 2:16-17 YBCV

Olufẹ mi ni temi, emi si ni tirẹ̀: o njẹ lãrin awọn lili. Titi ìgba itura ọjọ, titi ojiji yio fi salọ, yipada, olufẹ mi, ki iwọ ki o si dabi abo egbin, tabi ọmọ agbọnrin lori awọn oke Beteri.