O. Daf 97:10-12

O. Daf 97:10-12 YBCV

Ẹnyin ti o fẹ Oluwa, ẹ korira ibi: o pa ọkàn awọn enia mimọ́ rẹ̀ mọ́: o gbà wọn li ọwọ awọn enia buburu. A funrugbin imọlẹ fun olododo, ati inu didùn fun alaiya diduro. Ẹ yọ̀ niti Oluwa, ẹnyin olododo; ki ẹ si ma dupẹ ni iranti ìwa-mimọ́ rẹ̀.