O. Daf 94:1-2

O. Daf 94:1-2 YBCV

OLUWA, Ọlọrun ẹsan; Ọlọrun ẹsan, fi ara rẹ hàn. Gbé ara rẹ soke, iwọ onidajọ aiye: san ẹsan fun awọn agberaga.