O. Daf 92:13-14

O. Daf 92:13-14 YBCV

Awọn ẹniti a gbin ni ile Oluwa, yio gbà ni agbala Ọlọrun wa. Nwọn o ma so eso sibẹ ninu ogbó wọn: nwọn o sanra, nwọn o ma tutù nini