O. Daf 92:12-14

O. Daf 92:12-14 YBCV

Olododo yio gbà bi igi ọpẹ: yio dàgba bi igi kedari Lebanoni. Awọn ẹniti a gbin ni ile Oluwa, yio gbà ni agbala Ọlọrun wa. Nwọn o ma so eso sibẹ ninu ogbó wọn: nwọn o sanra, nwọn o ma tutù nini