O. Daf 89:47-48

O. Daf 89:47-48 YBCV

Ranti bi ọjọ mi ti kuru to; ẽse ti iwọ ha da gbogbo enia lasan? Ọkunrin wo li o wà lãye, ti kì yio ri ikú? ti yio gbà ọkàn rẹ̀ lọwọ isa-okú.