O. Daf 88:2-4

O. Daf 88:2-4 YBCV

Jẹ ki adura mi ki o wá si iwaju rẹ: dẹ eti rẹ silẹ si igbe mi. Nitori ti ọkàn mi kún fun ipọnju, ẹmi mi si sunmọ isa-okú. A kà mi pẹlu kún awọn ti o sọkalẹ lọ si ihò: emi dabi ọkunrin ti kò ni ipá.