O. Daf 88:1-3

O. Daf 88:1-3 YBCV

OLUWA Ọlọrun igbala mi, emi nkigbe lọsan ati loru niwaju rẹ. Jẹ ki adura mi ki o wá si iwaju rẹ: dẹ eti rẹ silẹ si igbe mi. Nitori ti ọkàn mi kún fun ipọnju, ẹmi mi si sunmọ isa-okú.