O. Daf 86:3-5

O. Daf 86:3-5 YBCV

Ṣãnu fun mi, Oluwa: nitori iwọ li emi nkepè lojojumọ. Mu ọkàn iranṣẹ rẹ yọ̀: Oluwa, nitori iwọ ni mo gbé ọkàn mi soke si. Nitori iwọ, Oluwa, o ṣeun, o si mura ati dariji; o si pọ̀ li ãnu fun gbogbo awọn ti nkepè ọ.