O. Daf 85:6-7

O. Daf 85:6-7 YBCV

Iwọ kì yio tun mu wa sọji: ki awọn enia rẹ ki o ma yọ̀ ninu rẹ? Oluwa fi ãnu rẹ hàn fun wa, ki o si fun wa ni igbala rẹ.