O. Daf 84:1-2

O. Daf 84:1-2 YBCV

AGỌ rẹ wọnni ti li ẹwà to, Oluwa awọn ọmọ-ogun! Ọkàn mi nfà nitõtọ, o tilẹ pe ongbẹ fun agbala Oluwa: aiya mi ati ara mi nkigbe si Ọlọrun alãye.