O. Daf 82:3-4

O. Daf 82:3-4 YBCV

Ṣe idajọ talaka, ati ti alaini-baba: ṣe otitọ si awọn olupọnju ati alaini. Gbà talaka ati alaini: yọ wọn li ọwọ awọn enia buburu.