O. Daf 71:20-21

O. Daf 71:20-21 YBCV

Iwọ ti o fi iṣẹ nla ati kikan hàn mi, ni yio si tun mi ji, yio si tun mu mi sọ si òke lati ọgbun ilẹ wá. Iwọ o sọ ọlá mi di pupọ̀, iwọ o si tù mi ninu niha gbogbo.