O. Daf 71:19-21

O. Daf 71:19-21 YBCV

Ọlọrun ododo rẹ ga jọjọ pẹlu, ẹniti o ti nṣe nkan nla: Ọlọrun, tali o dabi iwọ! Iwọ ti o fi iṣẹ nla ati kikan hàn mi, ni yio si tun mi ji, yio si tun mu mi sọ si òke lati ọgbun ilẹ wá. Iwọ o sọ ọlá mi di pupọ̀, iwọ o si tù mi ninu niha gbogbo.