O. Daf 70:1-2

O. Daf 70:1-2 YBCV

ỌLỌRUN, yara gbà mi; Oluwa, yara lati ràn mi lọwọ. Ki oju ki o tì awọn ti nwá ọkàn mi, ki nwọn ki o si dãmu: ki nwọn ki o si pada sẹhin, ki a si dãmu awọn ti nwá ifarapa mi.