O. Daf 65:12-13

O. Daf 65:12-13 YBCV

Papa-tutù aginju nkán: awọn òke kekèke fi ayọ̀ di ara wọn li àmure. Agbo ẹran li a fi wọ̀ pápá-tútù na li aṣọ: afonifoji li a fi ọka bò mọlẹ: nwọn nhó fun ayọ̀, nwọn nkọrin pẹlu.