O. Daf 62:5-6

O. Daf 62:5-6 YBCV

Ọkàn mi, iwọ sa duro jẹ de Ọlọrun; nitori lati ọdọ rẹ̀ wá ni ireti mi. On nikan li apata mi ati igbala mi: on li àbo mi; a kì yio ṣi mi ni ipò.