O. Daf 60:11-12

O. Daf 60:11-12 YBCV

Fun wa ni iranlọwọ ninu ipọnju: nitori pe asan ni iranlọwọ enia. Nipasẹ Ọlọrun li awa o ṣe akin: nitori on ni yio tẹ̀ awọn ọta wa mọlẹ.