O. Daf 54:4-5

O. Daf 54:4-5 YBCV

Kiyesi i, Ọlọrun li oluranlọwọ mi: Oluwa wà pẹlu awọn ti o gbé ọkàn mi duro. Yio si fi ibi san a fun awọn ọta mi: ke wọn kuro ninu otitọ rẹ.