O. Daf 54:3-5

O. Daf 54:3-5 YBCV

Nitoriti awọn alejò dide si mi, awọn aninilara si nwá ọkàn mi: nwọn kò kà Ọlọrun si li oju wọn. Kiyesi i, Ọlọrun li oluranlọwọ mi: Oluwa wà pẹlu awọn ti o gbé ọkàn mi duro. Yio si fi ibi san a fun awọn ọta mi: ke wọn kuro ninu otitọ rẹ.