O. Daf 51:15-17

O. Daf 51:15-17 YBCV

Oluwa, iwọ ṣi mi li ète; ẹnu mi yio si ma fi iyìn rẹ han: Nitori iwọ kò fẹ ẹbọ, ti emi iba ru u: inu rẹ kò dùn si ọrẹ-ẹbọ sisun. Ẹbọ Ọlọrun ni irobinujẹ ọkàn: irobinujẹ ati irora aiya, Ọlọrun, on ni iwọ kì yio gàn.