O. Daf 38:4-6

O. Daf 38:4-6 YBCV

Nitori ti ẹbi ẹ̀ṣẹ mi bori mi mọlẹ, bi ẹrù wuwo, o wuwo jù fun mi. Ọgbẹ mi nrùn, o si dibajẹ nitori were mi. Emi njowere; ori mi tẹ̀ ba gidigidi; emi nṣọ̀fọ kiri li gbogbo ọjọ.