Kò si ibi yíyè li ara mi nitori ibinu rẹ; bẹ̃ni kò si alafia li egungun mi nitori ẹ̀ṣẹ mi. Nitori ti ẹbi ẹ̀ṣẹ mi bori mi mọlẹ, bi ẹrù wuwo, o wuwo jù fun mi. Ọgbẹ mi nrùn, o si dibajẹ nitori were mi. Emi njowere; ori mi tẹ̀ ba gidigidi; emi nṣọ̀fọ kiri li gbogbo ọjọ. Nitoriti iha mi kún fun àrun ẹgbin; kò si si ibi yiyè li ara mi. Ara mi hù, o si kan bajẹ; emi ti nkerora nitori aisimi aiya mi.
Kà O. Daf 38
Feti si O. Daf 38
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 38:3-8
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò