O. Daf 34:3-4

O. Daf 34:3-4 YBCV

Gbé Oluwa ga pẹlu mi, ki a si jumọ gbé orukọ rẹ̀ leke. Emi ṣe afẹri Oluwa, o si gbohùn mi; o si gbà mi kuro ninu gbogbo ìbẹru mi.