O. Daf 29:10-11

O. Daf 29:10-11 YBCV

Oluwa joko lori iṣan-omi; nitõtọ, Oluwa joko bi Ọba lailai. Oluwa yio fi agbara fun awọn enia rẹ̀; Oluwa yio fi alafia busi i fun awọn enia rẹ̀.