O. Daf 28:6-7

O. Daf 28:6-7 YBCV

Olubukún ni Oluwa, nitoriti o ti gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ mi. Oluwa li agbara ati asà mi; on li aiya mi gbẹkẹle, a si nràn mi lọwọ: nitorina inu mi dùn jọjọ: emi o si ma fi orin mi yìn i.