Kọ́ mi li ọ̀na rẹ, Oluwa, ki o si tọ́ mi li ọ̀na titọ, nitori awọn ọta mi.
Kà O. Daf 27
Feti si O. Daf 27
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 27:11
7 Àwọn ọjọ́
Fun gbogbo àkókò òkunkun - ibẹrubojo ati sáà ìyè meji, àkò le ṣe alaimanilo imọlẹ gidgidi ni oniruru ọna. Láti fún wa ní Òye nípa ipò tí a wá tabi ọgbọn fún ìyípadà ilakọja ti ko dára fún réré. Eleyi ni jesu wá sí ayé láti musẹ. O sọ nínú ọrọ iṣẹ rẹ wípé "Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun Johanu 8:12.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò