O. Daf 22:2

O. Daf 22:2 YBCV

Ọlọrun mi, emi nkigbe li ọsan, ṣugbọn iwọ kò dahùn: ati ni igba oru emi kò dakẹ.