O. Daf 150:3-6

O. Daf 150:3-6 YBCV

Fi ohùn ipè yìn i: fi ohun-èlo orin ati duru yìn i. Fi ìlu ati ijó yìn i: fi ohun ọnà orin olokùn ati fère yìn i. Ẹ yìn i lara aro olohùn òke: ẹ yìn i lara aro olohùn goro: Jẹ ki ohun gbogbo ti o li ẹmi ki o yìn Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.