O. Daf 148:12-13

O. Daf 148:12-13 YBCV

Awọn ọdọmọkunrin ati awọn wundia, awọn arugbo enia ati awọn ọmọde; Ki nwọn ki o ma yìn orukọ Oluwa; nitori orukọ rẹ̀ nikan li o li ọlá; ogo rẹ̀ bori aiye on ọrun.