O. Daf 147:4-5

O. Daf 147:4-5 YBCV

O ka iye awọn ìrawọ; o si sọ gbogbo wọn li orukọ. Oluwa wa tobi, ati alagbara nla: oye rẹ̀ kò li opin.