O. Daf 147:3-5

O. Daf 147:3-5 YBCV

O mu awọn onirora aiya lara da: o di ọgbẹ wọn: O ka iye awọn ìrawọ; o si sọ gbogbo wọn li orukọ. Oluwa wa tobi, ati alagbara nla: oye rẹ̀ kò li opin.