O. Daf 127:3-5

O. Daf 127:3-5 YBCV

Kiyesi i, awọn ọmọ ni ini Oluwa: ọmọ inu si li ère rẹ̀. Bi ọfà ti ri li ọwọ alagbara, bẹ̃li awọn ọmọ igbà èwe rẹ. Ibukún ni fun ọkunrin na ti apo rẹ̀ kún fun wọn: oju kì yio tì wọn, ṣugbọn nwọn o ṣẹgun awọn ọta li ẹnu ọ̀na.