O. Daf 126:4-6

O. Daf 126:4-6 YBCV

Oluwa mu ikólọ wa pada, bi iṣan-omi ni gusu. Awọn ti nfi omije fún irugbin yio fi ayọ ka. Ẹniti nfi ẹkun rìn lọ, ti o si gbé irugbin lọwọ, lõtọ, yio fi ayọ̀ pada wá, yio si rù iti rẹ̀.