O. Daf 124:7-8

O. Daf 124:7-8 YBCV

Ọkàn wa yọ bi ẹiyẹ jade kuro ninu okùn apẹiyẹ: okùn já, awa si yọ. Iranlọwọ wa mbẹ li orukọ Oluwa, ti o da ọrun on aiye.