O. Daf 121:2-5

O. Daf 121:2-5 YBCV

Iranlọwọ mi yio ti ọwọ Oluwa wá, ti o da ọrun on aiye. On kì yio jẹ́ ki ẹsẹ rẹ ki o yẹ̀; ẹniti npa ọ mọ́ kì yio tõgbe. Kiyesi i, ẹniti npa Israeli mọ́, kì itõgbe, bẹ̃ni kì isùn. Oluwa li olupamọ́ rẹ: Oluwa li ojiji rẹ li ọwọ ọ̀tún rẹ.