EMI o gbé oju mi si ori oke wọnnì, nibo ni iranlọwọ mi yio ti nwa? Iranlọwọ mi yio ti ọwọ Oluwa wá, ti o da ọrun on aiye. On kì yio jẹ́ ki ẹsẹ rẹ ki o yẹ̀; ẹniti npa ọ mọ́ kì yio tõgbe. Kiyesi i, ẹniti npa Israeli mọ́, kì itõgbe, bẹ̃ni kì isùn. Oluwa li olupamọ́ rẹ: Oluwa li ojiji rẹ li ọwọ ọ̀tún rẹ. Orùn kì yio pa ọ nigba ọsan, tabi oṣupa nigba oru. Oluwa yio pa ọ mọ́ kuro ninu ibi gbogbo: yio pa ọkàn rẹ mọ́.
Kà O. Daf 121
Feti si O. Daf 121
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: O. Daf 121:1-7
6 Days
Prayer is a gift, an incredible opportunity to be in relationship with our Heavenly Father. In this 6-day plan, we will discover what Jesus taught us about prayer and be inspired to pray consistently and with great boldness.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò