O. Daf 119:73

O. Daf 119:73 YBCV

Ọwọ rẹ li o ti da mi, ti o si ṣe àworan mi: fun mi li oye, ki emi ki o le kọ́ aṣẹ rẹ.