O. Daf 118:8-9

O. Daf 118:8-9 YBCV

O ya lati gbẹkẹle Oluwa, jù ati gbẹkẹle enia lọ. O ya lati gbẹkẹle Oluwa, jù ati gbẹkẹle awọn ọmọ-alade lọ.