O. Daf 118:6-8

O. Daf 118:6-8 YBCV

Oluwa mbẹ fun mi, emi kì yio bẹ̀ru; kili enia le ṣe si mi? Oluwa mbẹ fun mi pẹlu awọn ti nràn mi lọwọ: nitorina li emi o ṣe ri ifẹ mi lori awọn ti o korira mi. O ya lati gbẹkẹle Oluwa, jù ati gbẹkẹle enia lọ.