O. Daf 118:5-7

O. Daf 118:5-7 YBCV

Mo kepè Oluwa ninu ipọnju: Oluwa si da mi lohùn ni ibi àye nla. Oluwa mbẹ fun mi, emi kì yio bẹ̀ru; kili enia le ṣe si mi? Oluwa mbẹ fun mi pẹlu awọn ti nràn mi lọwọ: nitorina li emi o ṣe ri ifẹ mi lori awọn ti o korira mi.