O. Daf 118:5-6

O. Daf 118:5-6 YBCV

Mo kepè Oluwa ninu ipọnju: Oluwa si da mi lohùn ni ibi àye nla. Oluwa mbẹ fun mi, emi kì yio bẹ̀ru; kili enia le ṣe si mi?