O. Daf 116:8-9

O. Daf 116:8-9 YBCV

Nitori ti iwọ gbà ọkàn mi lọwọ ikú, oju mi lọwọ omije, ati ẹsẹ mi lọwọ iṣubu. Emi o ma rìn niwaju Oluwa ni ilẹ alãye.